Ijọba ologun orilẹede Niger ti fofin de ileeṣẹ iroyin BBC fun oṣu mẹta lori ẹsun pe o n gbe iroyin ofege nipa orilẹede naa kiri. Ijọba ologun to wa lori oye lorilẹede naa sọ pe iru awọn iroyin ti BBC ...